Home Posts tagged NDDC
Yoruba
Àarẹ Muhammadu Buhari ti fèsì lórí ìwádi owó tó tó ogójì billiọnu naira tí àjọ tó wà fún ìdàgbàsókè agbègbè Niger Delta NDDC, èyítí ó ti ńfa awuyewuye láàrin ilé ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ àti àwọn adelé alásẹ àjọ náà. Àarẹ Buhari ti wá pàsẹ kí isẹ́ ìwádi tó yá ní kọ́nmọ́kánmọ́ ó bẹ̀rẹ̀ lórí isẹ́ […]Read More...
Yoruba
Ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé tó ńrísí idàgbàsókè ẹkùn Niger Dẹlta, NDDC, ti kanpá fún ọ̀gá àgbà bánki àpapọ̀ ilẹ̀ yíì Godwin Emefiele láti farahàn níwájú ilé. Alága, ìgbìmọ̀ ọ̀hún, ọ̀gbẹ́ni Nicholas Ossai, sọ fáwọn oníròyìn nílu Abuja, wípé àwọn ti gba àkọsílẹ̀ láti ilésẹ́ bánki àpapọ̀ lórí àwọn isẹ́ àkànse lẹ́kùn Niger Delta tótijẹ́ pípatì . […]Read More...
News Analysis
President Muhammadu Buhari recently signed into lawthe Nigerian Correctional Service Bill. The act changes the name of the Nigerian Prisons Service, NPS, to Nigerian Correctional Service. Senior Special Assistant on National Assembly Matters, Senator Ita Enang noted that the Nigeria Correctional Service is made up of two faculties, the custodial and non-custodial service. Read More...
Load More