Home Posts tagged NUPENG
Yoruba

Ẹgbẹ́ Elépo Rọ̀bì Àtafẹ́fẹ́ Gáasi Gbé Ìkìlọ̀ Kalẹ̀ Láti Máà Yọwọ Ìrànwọ́ Kúrò Lórí Epo

Ẹgbẹ́ àwọn elépo rọ̀bì àtafẹ́fk gáasi nílẹ̀ yíì, NUPENG, sọpé àmọ̀ràn ìgbìmọ̀ olùgbaniníyàjú lórí ètò ọrọ ajé tilé sẹ́ àarẹ, gbékalẹ̀ láti ìjáwọ́ ìrànwọ́ orí epo pẹtirol niwọ́n ni yóò kan tún pakún ìsòro tílẹ̀ Nàijírìa ńkojú. Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ lórí ìgbésẹ̀ náà, akọ̀wé àgbà àjọ NUPENG, ọ̀gbẹ́ni Olawale Alabi sọ fáwọn oníròyìn pé […]Continue Reading