Home Posts tagged ọdún Eid-el-Maulud
Yoruba

Àarẹ Buhari dáwọ́dùnú pẹ̀lú àwọn Mùsùlùmí lórí àyájọ́ ọdún Eid-el-Maulud

Bí àwọn Mùsùlùmí lórílẹ̀èdè yíì, se darapọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn lágbayé láti sayẹyẹ ọjọ́ ìbí ànọ́ọ̀bì. Àarẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì láti sàmúlò àkókò yíì, fíì nawọ́ ìfẹ́ sáwọn èèyàn wọn gẹ́gẹ́ bí àwòkóse ànọ́bì.  Nínú àtẹ̀gáde tí olùrànlọ́wọ́ pàtàkì fún àrẹ lórí ọ̀rọ̀ Continue Reading