Home Posts tagged ọ̀gbẹ́ni Oluwarotimi Akeredolu
Yoruba

Asòfin Kan Ti Dẹ̀bi Bọwọ Àwọn Ọ̀dọ́ Se Máà Ń Dilẹ Ru Àyíká Tíkò Dúró Re

Wọ́n ti sàpèjúwe bọwọ àwọn ọ̀dọ́ se máà ń dilẹ̀, gẹ́gẹ́ ìsoro kan gbogi tó ń kojú ilẹ̀ Nàijírìa nítorí báwọn ìsèjọba tóréjọjá kò se pèsè àyíká tó rọrùn fáwọn ọ̀dọ́ láti jígìrì sí ojúse wọn. Alákoso kejì fọ́rọ̀ ìpínlẹ̀ Niger Delta, Senator Ọmọtayọ Alasoadura ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì, nílu Àkúrẹ́ Continue Reading