Home Posts tagged Ọlawunmi Ọladeji
Yoruba

Asòfin Bèèrè Àfikún Ògbómọ̀sọ́ Nínú Orúkọ LAUTECH Tí Wọ́n Fẹ́ Yípadà

Àbá òfin láti sàyípadà ilé ẹ̀kọ́ gíga ìmọ̀ ẹ̀rọ Ládòkè Akintọla, LAUTECH, sí ilé ẹ̀kọ́ tí wọ́n ti ńkọ́ ìmọ̀ gbogbogbò ni wọ́n ti kà fún ìgbà kejì nílé ìgbìmọ̀ asòfin Ìpínlẹ́ ọ̀yọ́. Èyí ló jẹ́ nítorí ìwé kan tí Gómìnà Seyi Makinde fi sọwọ́ sílé ìgbìmọ̀ asòfin tí adarí ilé, ọ̀gbẹ́ni Adebọ Continue Reading