News Yoruba

Oga Olopa Kan Pe Fun Ife Laarin Olopa Atawon Araalu

Igbakeji oga olopa nile yi, ekun kokanla, Ogbeni Olasupo Ajani nfe kawon araalu dehin nidi iwa kikolu awon olopa tabi ilese olopa nigba yoowu ti awoo ba waye.

Ooga olopa ohun soro yi lasiko ipade re pelu awon torokan eyi towaye lolu ileese olopa, Ibadan.

 O salaye pe lati igba awoo ifehonnuhan ENDSARS, ibasepo laarin awon olopa ati awon araalu ti mehe, to si je okan latra ohun to n sokunfa bi aleekun se mba iwa odaran lorileede yi.

Saaju oga agba ileese olopa nipinle oyo, Arabinrin Ngozi Onadeko, sope pelu okan o jo kan ipenija tilese naa nkoju si; o n sa gbogbo ipa re lati ri daju pe Alafia joba nipinle Oyo.

Nigba toun n soro, alaga ajo to n risi ibasepo laarin ileese olopa ataraalu, PCRC, eka tipinle Oyo, Eniowo Peter Omofoye, seleri atileyin ati ibasepo to loorin ajo naa fun ilese olopa.

Makinde/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *