Home Posts tagged Olusegun Adeyemi
Yoruba

Àjọ NÓÀ pè fún àmúlò òfin tó wà fún òmìnira lílo àkọsílẹ̀ ìjọba

Àwọn tọrọ kàn ti pè fún àmúlò òfin tó wà fún sìsámúlo àwọn àkọsílẹ̀ láìsí ifoya. Ọ̀rọ̀ yi ló jé jáde níbi ìpàdé apero tí àjọ tó wà fún itaniji ará ìlú sí ojúṣe wọn NOA gbé kalẹ nilu Ilorin ńipinle Kwara. Oga agba àjọ NOA, ńipinle Kwara, Ogbeni Olusegun Adeyemi ṣàpèjúwe sìsámúlo òfin yí […]Continue Reading