Home Posts tagged Omi
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Fi Ọkàn Àwọn Èyàn Àwùjọ Balẹ̀ Lórí Àbá Òfin Lórí Omi

Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé kòsí on ìkọ̀kọ̀ kankan lórí àbá òfin lórí omi èyí tí ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ńgbé yẹ̀wò lọ́wọ́. Níbi àpérò kan nílu Abuja ni alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn àti àsà, Àlhájì Lai Mohammed àti alákoso fún ọ̀rọ̀ tóníse pẹ̀lú omi, ọ̀gbẹ́ni Suleiman Adamu, sọpé ọ̀pọ̀ àwọn tón kọminú lórí Continue Reading