Tag: orileede naijiria

  • Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ láti mágbega bá iná ọba

    Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ láti mágbega bá iná ọba

    Ìgbìmọ̀ alásẹ ìjọba àpapọ̀ ti buwọlu isẹ́ àkànse mẹ́rìndílógún lójúnà àti mú àgbéga báà iná mọ̀nà-mọ́ná nílẹ̀ yíì. Alákoso fóun àmúsagbára, Àlhájì Abubakar Aliyu sọ̀rọ̀ yíì fáwọn oníròyìn lẹ́yìn ìpàdé ìgbìmọ̀ alásẹ èyítí igbákejì ààrẹ ilẹ̀ yíì ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Osinbajo darí rẹ̀ nílu Abuja. Ó níì ìpèníjà kan gbogi tó ńkojú ìdúró ree iná mọ̀nàmọ́ná…