Home Posts tagged orileede
Yoruba

Ọgagun àgbà nilẹ̀ yí Yahaya gbósùbà fáwọn ikọ̀ tó ń kojú àwọn agbésùnmọ̀mì fún isẹ́ akọni wọn.

Ọgagun àgbà lórílẹ̀èdè yí, ọ̀gágun Faruk Yahaya ti rọ àwọn ológun ọ̀wọ́ kẹjọ iléèsẹ́ ológun ilẹ̀ yí pẹ̀lú àwọn ikọ̀ tí wọ́n pe ní Hadarin Daji pé kí wọ́n tẹpẹlẹ mọ́ igbokegbodo wọn nídi ogun gbigbe ti àwọn ukẹ agbesunmọmi. Eyi ló jẹyọ nínú àtẹ̀jáde tí olùdarí ẹ̀ka ètò ìkede fún iléèsẹ́ ológun Continue Reading