Home Posts tagged Oyo State Gemstone Market
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ńgbèrò Láti Kọ́ Ọjà, Nwọ́n Ó Ti Ma Ta Òkúta Olówó Iyebiye Nílu Ìbàdàn

Ìjọba àpapọ̀ ńgbèrò láti kọ́ ọjà ìgbàlódé tíwọ́n yóò ti máà ta òkúta olówó iyebíye nílu ìbàdàn. Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti fi ilẹ̀ saréè méjì kalẹ̀ fún isẹ́ àkànse náà. Alákoso fún ìdàgbàsókè ohun àlùmọ́nì, Ọ̀gbẹ́ni Ọlamilekan Adegbitẹ sọ èyí lágbègbè Ọjọọ, ní’jọba ìbílẹ̀ Akinyẹle níbi ayẹyẹ Continue Reading