Home Posts tagged SIM Card
Yoruba

Ìjóba Àpapọ̀ Sàfíkún Àkókò Lórí Sísọ Nọ́mbá Ìdánimọ̀ Ọmọilẹ̀ Yí Mọ́ Ẹ̀rọ Ìbánisọ̀rọ̀ Papọ̀

Ìjọba àpapọ̀ ti sàfikún àsìkò ti àwọn ènìyàn ní láti so nọ́mbà ìdánimọ̀ ọmọ ilẹ̀ yí NIN, wọn mọ́ ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ wọn títí di ọjọ́ kankàndílógún osù kini ọdún 2021 fún oníruru ìsọ̀rí àwọn oníbarà ilé isẹ́ ìbáẹnisọ̀rọ̀. Alákoso fọ̀rọ̀ ìbánisọ̀rọ̀ nílẹ̀ yí, Ọ̀mọ̀wé Isa Pantami ẹnití ó sọ̀rọ̀ yí Continue Reading