Home Posts tagged Venerable Dan Oyewole
Yoruba

Àlúfà rọ àwọn ọmọlẹ̀yìn Krístì láti gbé ìgbé-ayé íbẹ̀rù Ọlọ́run

Gbígbé ìgbé ayé tó ní ìtumọ̀ pẹ̀lú ìbẹ̀rù Ọlọ́run ni ó yẹkí ó lékè ọkàn gbogbo ènìyàn tó bá wà láyé. Venerable Dan Oyewọle tilé ìjọsìn St Mark Anglican Church, Olómi nílu ìbàdàn ló sọ̀rọ̀ yí nínú ìwásù rẹ̀ níbi ìsìnkú alága tẹ́lẹ̀rí fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Shooting Stars tìlú ìbàdàn, alàgbà Bọde Oyewọle. Venerable Oyewọle […]Continue Reading