Yoruba

Onimo nipa Ayika gbamoran lori imototo

Onimo nipa oro ayika, Ogbeni Abiodun Tijani ti ro awon eeyan ile yii lati ridajupe ayika won mo toni-toni nigbagbogbo.

Onimo ohun so eyi di mimo loja bodija nilu Ibadan nibi iwode lati samin, ayajo ilera ayika fun todun yii.

Ogbeni Tijani, enito tokasi pe ayika tomo toni-toni ma nfa oju awon oludokowo mora, wa gba awon ontaja niyanju lati kin ijoba leyin nidi fifese imotootoo ayika mule.

Akori ayajo ilera ayika fun todun yii, ipenija ayipada oju ojo, akoko fun iduro re imototo ati ilera lagbaye.

Ogunkola/Famakin

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *