Yoruba

Ijoba Apapo f’okan awon osise bale lori sisan owo osu tuntun

Ijoba apapo sope ohun yoo fi ooto inu ati akoyawo yanju ibere awon osise lori alekun owo osu awon osise towa nipele talekun owo naa okan.

Igbakeji aare, Ojogbon Yemi Osinbajo so eyi nigba ro nse ipade pelu awon adari titun egbe osise, TUC, tose abewo si nile aare nilu Abuja.

Awon oludari naa tare titun won Ogbeni Quadri Olaleye lewaju won, gboriyin fun ise awon adari egbe osise gbogbo pelu ijoba apapo.

Nigba to nsoro lori owu osise to wa lakso to kereju to nja roin-roin nle, igbakeji aare s’ope ose patakiki egbe osise so asoyepo pelu ijoba lori igbese naa.

Ninu oro re aare gbe TUC, enito ro ijoba apapo lati bere si san owo osu titun naa lakoko kiwon si mojuto oro abo nile yii.

Kemi Ogunkola/Modupe Toba

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *