Olùdarí àgbà ilé-isé Radio Nàìjíríà ẹkùn Ìbàdàn Alhaji Mohammed Bello, sọ pé àwọn tó ń ṣàgbékale ètò nilese náà gbodo lóye àwọn nkan tó ń ṣẹlẹ̀ láyìíká wọn, èyí tí yó jẹ́kí yàtò sáwọn toku, tíwọ́n yóò fi máa wà nípò iwájú.

Lópin ìpàdé apero olọ́jọ́ méjì tó dá lórí àgbékalè àwọn ètò gbogbo, tó wáyé nílese Premier F. M Iyaganku Ìbàdàn l’alaji Bello ti fìdí èyí múlẹ̀ pẹ̀lú àlàyé pé fi fowósowopo láàrín àwọn òṣìṣẹ́ nìkan lọ́nà kan gbogi láti múlese Radio Nàìjíríà di àkọ́kọ́ láàrín àwọn ilé isẹ taraalu yàn láàyò.

Alhaji Bello ní tabawo tí báwọn ilé isẹ igbohunsafefe ṣe pò lọ kánrin, wọ́n gbọ́dọ̀ fún kún akitiyan lórí àwọn ètò gbogbo tó ń jáde latori èrò ayélujára tó jé ojú òpó ilé isẹ náà.

Nígbà tó ń rọ àwọn òṣìṣẹ́ láti jẹ akosemose nidi ise tiwọn yàn láàyò àti nínú ẹ̀mí ifarajin fún ṣe, Alhaji Bello wá jẹjẹ pé, àwọn yóò gunle ètò ìdánileko ṣíṣe fáwọn òṣìṣẹ́, pẹ̀lú àfikún pé, akitiyan tinlo lọ́wọ́ láti magbega báwon ohun èlò àtàwọn irinse làwọn ẹ̀ka ilé isẹ náà tó wà káàkiri. 

Ìpàdé apero olọ́jọ́ méjì náà kase nílè loni. 

Mosope Kehinde /Yemisi Dada

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *