Home Posts tagged Iyaganku
Yoruba

Oga àgbà ilé-isé igbohunsafefe famonran síta lórí àwọn ètò tó ń jáde faraye gbó

Olùdarí àgbà ilé-isé Radio Nàìjíríà ẹkùn Ìbàdàn Alhaji Mohammed Bello, sọ pé àwọn tó ń ṣàgbékale ètò nilese náà gbodo lóye àwọn nkan tó ń ṣẹlẹ̀ láyìíká wọn, èyí tí yó jẹ́kí yàtò sáwọn toku, tíwọ́n yóò fi máa wà nípò iwájú. Lópin ìpàdé apero olọ́jọ́ méjì tó dá lórí àgbékalè àwọn ètò gbogbo, tó […]Continue Reading