Home Posts tagged Ijoba Apapo
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Sàwárí Egbẹ̀rún kan Àtàbọ́ Osise Pelu Ayederu Ìwé  Igbanisise

Ijọba àpapọ̀ ti sàwárí òsìsẹ́ tó lé ní ẹgbẹ̀rún kan àtàbọ́, tójẹ́ pé ìwé ìgbanisísẹ́ ayédèrú ni wọ́n lò láti darapọ̀ mọ́ isẹ́ ìjọba. Olórí òsìsẹ́ nílẹ̀ yí, ọ̀mọ̀wé Fọlasade Yẹmi-Ẹsan ló sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ nílu Abuja. Ọmọwe Yẹmi-Ẹsan sọpé ó lé ní ẹgbẹ̀rún kan àwọn èyàn tí wọ́n sàwárí ní ẹ̀ka Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ pè fún ìgbésẹ̀ fifòpin sí lílo ọmọdé nílòkulò

Ìjọba àpapọ̀ ti pè fún àmójútó tó péye láàrin àwọn tọ́rọ̀ kàn nídi àti fòpin sí lílo ọmọdé nílòkulò nílẹ̀ Nàijírìa. Akọ̀wé àgbà iléesẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó wà fún ọ̀rọ̀ òsìsẹ́ àti ìgbanisísẹ́, Dókítà Yerima Peter-Tarfa ló pèpè yí nílu Abuja lásìkò ètò ìdánilẹ́kọ tó wáyé fáwọn olùdarí ẹkùn àti alámojútó láwọn ìpínlẹ̀ nípa ètò […]Continue Reading
Yoruba

Ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ farun covid-19 pèfún sísọ́rase lákokò ọdún kérésìmesì

Ìgbìmọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ fárùn covid-19 rọ àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì láti sọdún kérésìmesì àti ìsinmi ọdún titun bótiyẹ. Alága ìgbìmọ̀ náà títún se akọ̀wé ìjọba àpapọ̀ ọ̀gbẹ́ni Boss Mustapha ló sọ̀rọ̀ yíì nínú àtàjáde nílu Abuja. Ọgbẹni Mustapha níì ó se pàtàkì, káwọn èèyàn mú ìgbésẹ̀ àbò wọn àti pípa àwọn ìlànà atẹle fárùn […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ láti mágbega bá iná ọba

Ìgbìmọ̀ alásẹ ìjọba àpapọ̀ ti buwọlu isẹ́ àkànse mẹ́rìndílógún lójúnà àti mú àgbéga báà iná mọ̀nà-mọ́ná nílẹ̀ yíì. Alákoso fóun àmúsagbára, Àlhájì Abubakar Aliyu sọ̀rọ̀ yíì fáwọn oníròyìn lẹ́yìn ìpàdé ìgbìmọ̀ alásẹ èyítí igbákejì ààrẹ ilẹ̀ yíì ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Osinbajo darí rẹ̀ nílu Abuja. Ó níì ìpèníjà kan gbogi tó ńkojú ìdúró ree iná mọ̀nàmọ́ná […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ lu ilẹ̀ Amẹrica lọ́gọ ẹnu lórí ìrànwọ́ fún ìgbógun ti ìgbésùmọ̀mí

Àarẹ Muhamadu Buhari ti fẹ̀mí ìmoore hàn sí àwọn alásẹ ilẹ̀ Amẹrica lórí bí wọ́n se gba ilẹ̀ Nàijírìa láàye láti ra ohun ìjagun fún gbígbógun ti ìgbésùmọ̀mí tó fimọ́ ètò ìdánilẹ̀kọ tíwọ́n se fáwọn ọmọ ogun ilẹ̀ Nàijírìa. Àarẹ Buhari sọ̀rọ̀ náà nílu Abuja lásìkò tón gbàléjò akọ̀wé ìjọba ilẹ̀ Amẹrica, ọ̀gbẹ́ni Anthony Blinker. […]Continue Reading
News Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ti Parí Ìlànà Láti Gba Owó Tó Ó San Fá’wọn Dókítà Kan Lọ́nà Àitọ́

Ìjọba àpapọ̀ ti setán láti gba owó tó wọ ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ milliọnu naira tí wọ́n sesi san fun àwọn Dókítà onímọ̀ ìsègùn tó lé ní ẹdẹgbẹta níye yíká orílẹ̀ èdè yí. Alákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ìgbanisísẹ́ Sẹnatọ Chris Ngige ló sọ̀rọ̀ yí di mímọ́ lásìkò tón dáhun ìbere látọ̀dọ̀ àwọn akọ̀ròyìn nílu Abuja. Alákoso se lálàyé […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Apapọ̀ Ti Gbé Orùkọ́ Ipínlẹ̀ Mọ́kànlélógún Jáde Ti Wọ́n Yo Ni Ibùdó Iselọ́jọ̀ Fún Kíkó Eran Jẹ̀

Pẹ̀lú bí ìgbésẹ̀ láti mú àyípadà dé bá ńkan ọ̀sìn nílẹ̀ yí, ìjọba àpapọ̀ ti ní kí ibùdó tí wọ́n yo ti ma kẹ́ran jẹ̀, tí wọ́n yà sọ́tọ̀, kó gbérasọ, nípinlẹ̀ mọ́kàndínlógún láriwá ilẹ̀ yí, tófimọ́ ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ àti Ògùn lẹ́kùn ìwọ̀ orun gúsù ilẹ̀ yí. Nígbà tón sọ̀rọ̀ nílu Abuja, lásìkò ìpàdé ẹlekẹrin […]Continue Reading
News Yoruba

Ijoba Apapo Sekilo Fawon Omo Orileede Yi Kan, Lati Yago Kuro Nidi Gigunle Irin-Ajo Lo Sawon Orileede Tarun Covid-19 Eleeketa N Ba Finra

Ijoba apapo orileede yi ti sekilo fawon omo orileede yi, lati yago kuro nidi gigunle awon irinajo lo sawon ilu ti ibesile kokoro aarun covid-19 n bafinra fun igba keta, papa  julo ile India nibi to ti gbile jula. Bakanna, lo tun menuba ile South Africa, Turkey ato rileede Braizil ninu oro igbanniyanju lori oro […]Continue Reading