Yoruba

Gomina Fayemi Pase Ayewo Arun Covid-19 Fawon Akeko N’ipinle Ekiti

Gomina ipinle Ekiti, Omowe Kayode Fayemi ti pase ayewo arun COVID-19, awon oluko atawon akeko kokan lati mu adinku ba itankale aarun COVID-19 n’ipinle naa.

Gomina Fayemi ninu oro re lori afefe fawon eeyan, tokasi pe igbese ayewo arun, ti safihan opo arun COVID-19, to si sope igbese naa yoo tan de awon ile-eko.

O salaye pe ijoba ti safomo awon ile-iwe ijoba ti igbese is n je gbigbe lati san awon igboo, lati mu eto eko rorun pelu ayika too yee koroo.

Omowe Fayemi, fikun pe ijoba ti pese awon ohun tooye feeto abo lori arun COVID-19 laon ile-iwe ti igbimo kan siti je gbigbe kale lati maa sabewo sawon ile-eko.

Elizabeth Idogbe/Amos Ogunrinde