September 18, 2020
Yoruba

Ilewosan Nla UCH Bere Atileyin Lori Amugboro Itoju Awon Toni Aisan Covid-19

Won tisefilole ibusun ogun sibudo ton risi itoju arun lolokan ojokan nile ikose isegun nla UCH Ibadan gegebi bi ara igbese akitiyan fun itoju awon toni arun Covid-19.

Nigba ton siso loju awon ibusun naa, Gomina Ipinle Oyo, Onimoero Seyi Makinde, eniti Alakoso Feto Ilera, Dokita Bashir Bello soju fun, sope ise akanse naa sile iwosan nla UCH ati omiran to wa ni ilewosan ijoba Ring Road Ibadan, yoo seranlowo lati magbega beto ilera ni Ipinle Oyo.

Onimo Isegun Oyinbo Agba nilewosan nla UCH, Ojogbon Jesse Otegbayo tokasi pe ko si ijoba naa tole dan8ikan mojuto awon isoro to n suyo leka eto ilera, nitorinaa lofi se pataki kawon eeyan awujo lowosi gege bi ireti ojo ola orile ede.

Ninu oro tie, eni to sagbateru ibusun naa, Oloye Tunde Afolabi, eniti olori osise tele ni orile ede yii, ojogbon Oladapo Afolabi femi imore han lori bose lanfani lati se fawujo.

Yara alaisan meta lowa nibudo itoju awon ton gabatoju lowo farun Covid-19, ti gbogbogboo kan tawon osise noosi pelu awon irinse miran towa fun itopinpin awon alaisan.

Ololade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *