-
Ilewosan Nla UCH Bere Atileyin Lori Amugboro Itoju Awon Toni Aisan Covid-19
Won tisefilole ibusun ogun sibudo ton risi itoju arun lolokan ojokan nile ikose isegun nla UCH Ibadan gegebi bi ara igbese akitiyan fun itoju awon toni arun Covid-19. Nigba ton siso loju awon ibusun naa, Gomina Ipinle Oyo, Onimoero Seyi Makinde, eniti Alakoso Feto Ilera, Dokita Bashir Bello soju fun, sope ise akanse naa sile…