Ajo elepo robi ile yi, NNPC ti kilo fun awon eniyan alti mase foya lori rira awon eroja epo robi.

Ikilo yi lo waye latari iberu to be sile nilu Abuja ati agbegbe re bi awon eniyan ti se nto ra epo.

Agbenuso ajo NNPC, Ogbeni Kehinde Obateru ni ko si idi kankan lati ko okan soke nitori won ni eroja to too lo nile.

 Ogbeni Obateru salaye wipe bi awon gomina ti se nde ofin isede bayi gbogbo nkan to nip e pada bo sipo laipe.

O wa tenumo wipe ajo NNPC ni eroja to too o lo, to wa ro awon oni ile epo lati mase gba epo pamo.

Oluwayemisi Dada

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *