News Yoruba

Ìjọba àpapọ́ sèlérí mímúkí pàsí-pàrọ̀ owó ilẹ̀ òkèrè túbọ̀ rọrùn síì.

Igbákejì àarẹ ille yíì, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo sọ pé, ìjọba àpapọ̀ ti ń sisẹ́ pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́ àpapọ́ orílẹ̀dè yíì, CBN, fún isẹ́ akoyawo àti níní ànfàní si síse pàsí pàrọ̀ owó ilẹ̀ òkèrè pọ̀ọsi.

Nígbà tó ń báwọn adarí olókoowò nílẹ̀ faransé sọ̀rọ̀ nílu Abuja, lọ̀jọ̀gbọ́n Ọsinbajo ti sọ́ọdi mímọ̀ pé, ìjọba ń sakitiyan látiri dájú pé wọ́n mú àgbénde bẹ́ka okòowò síse pàsípàrọ̀ owó.

Kò sài sọ́ọdi mímọ̀ pé, owó bí trilliọnu méjì náirà tíjọba yáà lọ́wọ́ ilé ìfowópamọ́ náà, láti fi wójùtú sẹ́ka iná ọba orílẹ̀dè yíì, ló ti ń ri yánju diẹ diẹ báyíì.

Pẹ̀lú àlàyé pé ìjọba ń nawọ́ sẹ́ka iná ọba láti fi sàtúnse ẹ̀ka ohun àmúsagbára.

Ibrahim/Idogbe       

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *