Home Posts tagged Yẹmi Ọsinbajo
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Se Ìfilọ́lẹ̀ Ètò Ìdàgbàsókè Ọrọ̀ Ajé Láwọn Ìpínlẹ̀

Igbákejì Àrẹ, Yẹmi Ọsinbajo ti kéde ìdásílẹ̀ ètò ìdàgbàsókè mẹ́fà èyí tí ìjọba àpapọ̀ fẹ́ gùnlé láwọn lẹkun kọ̀kan nílẹ̀ yí, láti lè mú kí àgbéga débá ọrọ̀ ajé láwọn  ìpínlẹ̀. Igbákejì Àrẹ kédeyi lásìkò àpérò ilẹ̀ adúláwọ̀ níbi tí àtúntò fọ́dún 2022 yo ti wáyé nílu Abuja. Ọjọgbọn Ọsinbajo sọ Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Fẹ́ Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Fífòpinsí Lásigbo Akọ-Sákọ Àti Abo-Sábo

Igbákejì olórí orílẹ̀èdè yí, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo, ti fìdùnú rẹ hàn sí bí ìwà lásígbo akọsákọ òhun abosábo se ń díkùn nípasẹ̀ ìdásí àwọn asáàjú àwùjọ àtàwọn olórí ẹlẹ́sìnjẹsin nílẹ̀yí. Ó sọ̀rọ̀ náà nílu Abuja lásìkò tó ń sọ̀rọ̀ níbi è[tò kan tó wáyé. Ọjọgbọn Ọsinbajo tí alákoso fọ́rọ̀ àwọn obìnrin, Dame Pauline Tallen sojú […]Continue Reading
News Yoruba

Ìjọba àpapọ́ sèlérí mímúkí pàsí-pàrọ̀ owó ilẹ̀ òkèrè túbọ̀ rọrùn síì.

Igbákejì àarẹ ille yíì, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo sọ pé, ìjọba àpapọ̀ ti ń sisẹ́ pẹ̀lú ilé ìfowópamọ́ àpapọ́ orílẹ̀dè yíì, CBN, fún isẹ́ akoyawo àti níní ànfàní si síse pàsí pàrọ̀ owó ilẹ̀ òkèrè pọ̀ọsi. Nígbà tó ń báwọn adarí olókoowò nílẹ̀ faransé sọ̀rọ̀ nílu Abuja, lọ̀jọ̀gbọ́n Ọsinbajo ti sọ́ọdi mímọ̀ pé, ìjọba ń sakitiyan […]Continue Reading