Sultan ti Sokoto, Àlhájì Saad Abubakar ti pè fún ìpàdé àpérò láti yanjú ọ̀kan òjọ̀kan ìpèníjà tó ń kojú orílẹ̀èdè yíì.

Ọba alayé ọ̀hún pe ìpèe yíì níbi ìpàdé ẹlẹmẹrinlọdun fáwọn oníruru ẹ̀sìn NIREC, nílu Abuja.

Àlhájì Abubakar sọpé ipò ètò àbò lẹ́kùn ìwọ̀ọ oorùn ilẹ̀ yíì ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé ọ̀pọ̀ èeyàn ti sákúrò nílé kóowá wọn nítorí ìbẹ̀rù-boojo.

Sultan tọ́kasi pé àsọyépọ̀ àláfìa gbọdọ̀ wáyé larin àwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì tóò le wáà ojútu sí àwọn ìpèníjà lẹ́ka ètò àbò.

Net/Elizabeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *