Home Posts tagged Ilé asòfin kejì
Yoruba

Ilé asòfin kejì bèrè fájọsepọ̀ àwọn tọ́rọkàn lórí àbá òfin tóníse pẹ̀lú pẹtirolu

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi gbajabiamila ti rọ àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lẹ́ka afẹ́fẹ́, Gas láti sisẹ́ papọ̀ pẹ̀lù ìjọba fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka ọ̀hún, lọ́nà àtijẹ́ kò so èso rere. Ọgbẹni Gbajabiamila ló gbọrọ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀ lákokò ikọ̀ asojú kan látile se tón ri sọ́rọ̀ afẹ́fẹ́ Gas Continue Reading
Yoruba

Ilé asòfin kejì pé fun ìdènà ìrìnàjò àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lẹ́ka ètò ìlera sílẹ̀ òkèrè

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì ti rọ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì, láti dènà ìrìnàjò àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ elétò ìlera sáwọn ilẹ̀ òkèrè nínú àbá kan tọ́mọ ilé asòfin náà, ọ̀gbẹ́ni Ganiyu Johnson ló ti késí ilé isẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ isẹ́, ìgbanisísẹ́ àti bọ́wọ́ isẹ́ se ń yáasí láti se ìpèsè isẹ́, kíwọ́n sì ságbékalẹ̀ àwọn […]Continue Reading