Home Posts tagged ẹ́ka ètò ìlera
Yoruba

Ilé asòfin kejì pé fun ìdènà ìrìnàjò àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lẹ́ka ètò ìlera sílẹ̀ òkèrè

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì ti rọ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀dè yíì, láti dènà ìrìnàjò àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ elétò ìlera sáwọn ilẹ̀ òkèrè nínú àbá kan tọ́mọ ilé asòfin náà, ọ̀gbẹ́ni Ganiyu Johnson ló ti késí ilé isẹ́ tó ń rí sọ́rọ̀ isẹ́, ìgbanisísẹ́ àti bọ́wọ́ isẹ́ se ń yáasí láti se ìpèsè isẹ́, kíwọ́n sì Continue Reading