Yoruba

ijoba apapo yo se ifilole iforuko sile dukia ti won ti gba pada – Agbejoro Agba

Agbejoro agba Ogbeni Dayo Apapta sope laipe yi ni ijoba apapo yo se ifilole iforuko sile lori ero ayelujara lori dukia ti won ti gba pada.

Ogbeni Apata so pe igbimo to nrisi isakoso lori awon dukia ijoba ti won gba pada ni yo sise naa.

Lasiko ti agbejoro agba lo se abewo si oluileese ajo ton gbogunti sise owo ilu kumo-kumo ati eto oro aje nilu Abuja ni o ti siso loju oro yi.

Ogbeni Apata ti se Alaga igbimo naa, soro idaniloju pe ijoba apapo yo ri awon dukia yi lo pada lona ti yose ara ilu lanfani.

Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *