Yoruba

Àwọn Akọ́sẹmọ́sẹ́ Dókítà Tó Ń Wa Imọkunmọ Ní Ilé Ìwòsàn Ńlá U.C.H Gùnlé Ìyansẹ́lódì

Àwọn aláisan níléwòsàn ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn òyìnbò U.C.H, nílu Ìbàdàn niwọ́n kòrí ìtọ́jú gbà lóni pẹ̀lú báwọn Dókítà akọ́sẹmọ́sẹ́ tónwá imọkunmọ segùnlé ìyansk lódì nítorí àisan owo àjẹmọ́nú wọn.

Akọ̀ròyìn ilé isẹ́ Radio Nigeria jábọ̀ pé, àwọn Dókítà ọ̀hún kọ̀ láti dá àwọn aláisan loun, nítorí tiwọn kòrí owó àjẹmọ́nú osù mẹ́ta sẹ́yìn gbà.

Ibọmọr/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *