Home Posts tagged U.C.H
Yoruba

Àwọn Akọ́sẹmọ́sẹ́ Dókítà Tó Ń Wa Imọkunmọ Ní Ilé Ìwòsàn Ńlá U.C.H Gùnlé Ìyansẹ́lódì

Àwọn aláisan níléwòsàn ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn òyìnbò U.C.H, nílu Ìbàdàn niwọ́n kòrí ìtọ́jú gbà lóni pẹ̀lú báwọn Dókítà akọ́sẹmọ́sẹ́ tónwá imọkunmọ segùnlé ìyansk lódì nítorí àisan owo àjẹmọ́nú wọn. Akọ̀ròyìn ilé isẹ́ Radio Nigeria jábọ̀ pé, àwọn Dókítà ọ̀hún kọ̀ láti dá àwọn aláisan loun, nítorí tiwọn Continue Reading
News Yoruba

Onímọ̀ ìsègùn sàtẹnúmọ́ ìdí fún ìtọ́jú ojú

Àwọn ọmọ olẹ̀ yí ni wọ́n ti gbà lámọ̀ràn láti máà sàyẹ̀wò ojú wọn ó kéré tán léèkan lọ́dún láti léè tètè kẹ́ẹ̀fín bí ojú bá ní ìpèníjà. Olùtọ́jú ojú tíì tún se igbákejì ọ̀gá àgbà lẹ́ka olùtọ́jú aláisan nílé ìwòsàn ẹ̀kọ́sẹ́ ìsègùn U.C.H., arábìnrin Abiọla Agatha ló fàmọ̀nràn yi síta nígbàtí ó ńbá akọ̀ròyìn ilé isẹ́ prẹmier F.M sọ̀rọ̀ n;ilu ìbàdàn. Continue Reading