Yoruba

Ajo eleto idibo se ileri ibo ti ko leja nba-kan ninu ni ipinle ekiti

Ajo eleto idibo nile yi inec, ti so pe gbogbo ipa to wa ni ikawo re ni yoo sa lati se to idibo ti koni eja nba kan nu ni ipinle ekiti .

Alakoso fun ajo inec lekun iwo orun gusu omowe adekunle ogunmola lo so oro yii ni ilu ado – ekiti nigbati ohun gba  awon eroja eto idibo na .

O si sope ajo na ti gbaradi fun eto idibo pelu oro idaniloju pee to idibo na yio yori sir ere .

Ninu oro alakoso fun ajo inec  ni ipile ekiti omowe adeniran tella sope awon on elo fun eto idibo niwon yoo gbe lo si awon ibudo ti won yoo tilo loju ojo

Akoroyin ile ise radio Nigeria jabo pee kun ila orun ekiti kinni loni wodu  marun pelu ibudo idibo metadilogoji  awon to si ti fi  oruko sile je egberun lona metalelogun ati otalelegbeta le mewa

Amos/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *