Home Posts tagged Ajo eleto idibo
News Yoruba

Àjọ elétò ìdìbò tún bẹ̀rẹ̀ ìforúkọsílẹ̀ odìbò jákèjádò ilẹ̀ yí

Ajọ eléto ìdìbò ill yí INEC, ti bẹ̀rẹ̀ ètò ìforúkọ olùdìbò padá, ní ìpalẹ̀mọ́ fún ètò ìdìbò gbogbogbò ọdún 2023.Alága àjọ elétò ìdìbò nílẹ̀ yí, ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ pẹ̀lú àlàyé wípé àjọ náà ti se àlékún ibúdò tuntun, èyí tí wọ́n si ti se adayanri ẹlẹ́gbẹ́jẹ́gbẹ́ bíì mọ́kànlẹ́lọ́gbọ̀n ti yóò tọpinpin […]Continue Reading