Ijoba apapo ti sapejuwe segesege ti owo epo petirolu n se lawon ileepo kan larin agbegbe kan lorileede yi gege bi dukuu ti an ko tii ri ojutu e laarin awon awako epo atawon to gbawon sise.

 Oludari agba ileese , elepo ile yi NNPC ogbeni mel kyari lo so asodaju oro yi nilu Abuja pelu ileri pe laipe laijinaa ni own yoo was ojutu si oro naa.

Ogbeni kyari lodi epo robi to fe dabi eni pe o won mo bi awon awako epo naa se n wo ise niran, nipa bi won se n fi ehonu han lori eto won ti an n bere fun.

 O fi gbogbo awon ile yi lokan bale pea won awako epo naa ti so iynase loodi won ro fun ose kan.

Oludari agba ajo NNPC slaye wi pe  awon awako epo naa ti pada senu ise jake jado ile yi.

O se afikun e pae ohun ti won senu ko le lori pelu awon awako epo to n fi ehonu han naa yio fun awon alase lanfaani ati sori ikoko sodunrun lori ohun to won n bere fun.

Net/Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *