News Yoruba

Ile-Ise Omo Ologun Ile Yii, Jeje Eto Abo To Gbopon Lawon Ibudo Ifinimole Ajo Asinruule NYSC

Ile is omo Ologun ile yii, ti jeje eto abo to gbopon lawon ibudo ifinimole atawon ilegbe awon agunbaniro tajo to n risi sise isinruulu awon ajo, NYSC, lekun ilaoorun gusu, nibi teto abo ko ti rese wale.

Oga agba fun ileese omo ologun owo kejilelogun nipinle Enugun, Ogagun Agba Taoreed Lagbaja, lo fowo idaniloju yi soya nilu Enugun lakoko ti oludari ajo NYSC, lekun naa, Arabinring Ngozi Nwatarali wa sabewo si lofisi re.

Ogagun agba Lagbaja wa ke sawon asaju kookan lati gbogbo ibudo ajo to n risise isinruule nipinle naa, kiwon satojopo oruko gbogbo awon ilegbe awon agunbaniro naa to n be lekun ila oorun gusu kiwon si fowosowopo pelu awon okanojokan awon omo ologun fun ipese eto abo to loorin.

   Net/Wojuade

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *