Ijoba apapo orileede yi ti sekilo fawon omo orileede yi, lati yago kuro nidi gigunle awon irinajo lo sawon ilu ti ibesile kokoro aarun covid-19 n bafinra fun igba keta, papa julo ile India nibi to ti gbile jula.
Bakanna, lo tun menuba ile South Africa, Turkey ato rileede Braizil ninu oro igbanniyanju lori oro irin ajo.
Alabojuto agba fun igbimo amuseya ile-ise aare tiwon gbekale foro covid-19, omoowe Mukhtar Muhammad lo siso loju oro yii nibi ipade awon oniroyin to waye nily Abuja.
Bee lo tun sekilo fawon omo orileede yi kan tiwon fo dengbere mawon ofin atilana to dena itankanle arun covid-, kiwon sora se nitori pe, arun naa ko tii kase nile tan.
Omowe Muhammad wa tokasi pe, ofin titakete lawujo opo ero, atiwiwo ibomu, siwa digbi, lawon ojutaye bi oja, ibudo igbafe awon ile itaja igbalode to fi mawon ibomiin lati itankanle kokoro arun covid-19 patapata.
Net/Wojuade