News Yoruba

Tinubu Pelu Awon Agba Egbe Oselu APC Pe Fun Ojutu Si Awon Ipenija Orileede Yii

Adari egbe oselu APC, Asiwaju Bola Tinubu ti sabewo saare Mohammadu Buhari, nibi to ti bere fun idahun kiakia sawon ipenija to nkoju awon eeyan orileede yii.

Gomina tele nipinle Eko ohun, enito kowo rin pelu adele alaga tele fegbe oselu naa, Oloye Bisi Akande ba awon oniroyin soro leyin ipade alatilekun mori se pelu Aare nilu Abuja.

O wa ro awon eeyan ile Nigeria lati fowosowopo pelu ijoba apapo nidi wiwa ojutu sokan o jokan ipenija to nsuyo, pelu alaye pe, ipenija eto abo to nkoju orileede yi, kise orileede yi nikan lo nkoju ipenija yii, pelu alaye pe gbigbe igbese lati wojutu si se pataki. Asiwaju Bola Tinubu wa sapejuwe igbora eni ye ipinuokan, abo to duro re ati jije ki awon araalu mo boose nlo gege bi ara awon ohun tile yi nilo lati jajabo lowo ipenija.

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *