Gomina ipinle Ondo, Ogbeni Rotimi Akeredolu so pe, isejoba oun ti setan lati sedasile ekun idokowo kan silu Akure, eyi ti yoo foju awon oludokoowo mora lati wa dase aje sile, pelu mimu amigbooro be to oro Aje yika ipinle Ondo.

Ilu Akure ni Gomina ti sore yii di mimo lakoko t’awon alase eka to nri soro okoowo, ti idase aje sile, tiwakusa tofun eto ogbin wa sabewo sodo re.

Gomina Akeredolu salaye pe, idasile ekun naa lowa lara afojusun eto isejoba re, latiridaju pe ipinle di ilu idokoowo fawon onise aje yika ipinle naa ko sai ke sawon eka Aladani lati satileyin feto isejoba re, lona ati samulo awon inkan amusoro to wanle nipinle ohun daada, fagbega eto oro aje re, ti yoo si se ipese ise lopo yanturu fawon eeyan ti ko ri se nipinle naa.

Net/Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *