Ijoba ipinle osun ti tẹwọgba abẹrẹ ajẹsara lati dena itankalẹ arun COVID-19 toto fun eyan to le ni ẹgbẹrun mẹta din ladọta, latọdọ ijọba apapọ.

Igbakeji Gomina Ipinlẹ Ọsun, Ọgbẹni Benedict Alabi, lo jẹ kọrọ naa di mimọ, l’asiko iside, gbigba abẹrẹ ajẹsara ohun lelekeji nilu Osogbo.

Ọgbẹni Alabi sọ pe, abere ajesara naa, ni ko to un kan mọ ni gbogbo agbaye, pẹlu bi awọn to fẹ gba sen pọsi.

Igbakeji Gomina se lalaye pe isejọba oyetọla ni o tin polongo lalala lori ewu to rọ mọ arun ọhun lori awọn opo ibanisọrọ, tọ si rọ gbogbo eyan awujọ lati ma tele gbogbo awọn ilana to rọ mọ didẹkun itankalẹ COVID-19.

Bakana lo tun gba awọn eyan miyanju lati fi to ajọ eleto ilera lati ti wọnba kẹfin amin ara to jọ ti covid-19, ki wọn le tetegba itọju.

Ọgbẹni Alabi fikun pe, ipinlẹ Ọsun ni ajọsepọ pẹlu ajọ eto ilera apapọ, ajọ lilo, Ajo Eleto Ilera Agbaye, W.H.O., tofimọ awọn tọrọkan yooku lati gbogun ti itankalẹ arun COVID-19. Adenitan Akinọla/Ọlọlade Afọnja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *