Yoruba

Ajo FIRS Pe Fun Sisan Owo Ori Loore Koore

Oludari eka ilana owo ori sisan nileese ijoba apapo to n ri si liana ipawowole labenu, FIRS, Ogbeni Temitayo Orebajo ti soo di mimo pe o ye ki awon elegbejegbe maa ri daju pe won foruko sile pely ijoba nitori owo ori sisan, ki won si gba number idanimo pe won san owo ori sapo ijoba.

Ogbeni Orebajo sipaya oro yi nilu Abuja lasiko eto kan to waye.

O soo di mimo pe igbese naa ni yoo mu ki igboraeniye wa ati idi pataki ti won fi n san owo ori.

Ogbeni Orebajo tenumo pe liana owo ori sisan fawon elegbejegbe se pataki nidi ati le ni akosile iye ti awon osise je pelu liana ati mo bi eto owo ori sisan se n lo.

O salaye wi pe ileese tabi elegbejegbe to ba kuna lati tele liana owo ori sisan yoo fara gbegba ofin.

Babatunde Salaudeen/Aminat Ajibike

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *