Kile Nigeria le fa awon oludokowo loju mora si, o gbodo dewo lori awon owo to room idokowo ohun amayederun.

Oga agba ajo olokoowo agbaye WTO, Omowe Ngozi Okonjo iweala lo soro iyanju naa nibi eto sise agbeyewo iromo sisesi awon alakoso to sese pari nilu Abuja.

Omowe Okonjo-Iweala ko sai tun woye pe nise loye ki adinku de ba owo to room liana idokoowo to fi mo owo ori idokoowo ko le faaye gba opo idokoowo nileyi.

O salaye pe owo to room oro aje nile Nigeia lo gbenusoke yato si awon orileede to n pawo wole lopo yanturu.

Oga gba ajo olokoowo agbaye naa w ape fun sise atunse eto abo ile yi ko le faye gba waon oludokowo ile okeere ati tabele.

  

Fadahunsi/Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *