Alakoso feto abo, Ajagun feyinti Bashir Magashi, ti so pe koko koni gbomi gbeyin gba soso fawon to n se fayawo awon ohun ijagun kekeeke ati awon min nile yi.

Alakoso sope oro ohun se koko nitoripe awon ohun ijagun ohun lo n ro aiseto abo lagbara nile yi.

Gege bosewi, o ni ijoba apapo yoo ri daju pe ohun nawo gan ati gbigbe rele ejo awon towo palaba won ba segi lori oro naa.

O wa famin idaniloju re han si ajo awon ti ofin faye gba fun ikowole ohun ijagun lori afenuko iwojutu soro naa.

Fadahunsi/Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *