Yoruba

E tesiwaju ninu ise fun alaafia, ilosiwaju ati isokan ile Nigeria – Alufa Agba Ijo Methodist

Won ti ro awon eeyan nile Naijiria lati tesiwaju ninu sise ise fun alaafia ilosiwaju ati isokan ile yi, nitoripe kosi orile ede miran ti won le pe ni ti won.

Prelate ijo Methodist nile yi Omowe Samuel Kanu Uche lo soro amoran yi nilu Oyo lasiko abewo re yika ijo to wa loorile ede yi.

Omowe Kanu Uche tenumo pe, bi gbogbo eeyan nile niba wa ni isokan, yo mu kori leede yi le se kangbon pelu awon akegbe re yo ku lagbaye to si sope o ye ki ijoba gbe igbese lati wojutu si gbogbo awon ipenija lori ireje, iwojumi emi oju o to fimo awon nkan tawon eeyan foju sile fun latari latoodo ijoba.

Saaju, Alaafin ilu Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, ni o ti gba alajo Prelate laafin re, to si fi idinu han lori igbese aji ka won asiwaju esin ngbe lori mimu amugburo deba ibagbepo Alafia lagbegbe naa.

Aminat Ajibike/Ololade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *