Ilé ẹjọ́ gíga ìjọba àpapọ̀ yíì bẹ̀rẹ̀ ètò ìsinmi lẹ́nu isẹ láti ogúnjó oṣù yí lọ.

Nibamu pẹ̀lú atejade tí adajo àgbà ilé ẹjọ́ gíga ilẹ̀ yí òundajo John Tsoho fi síta, igbese ipalemo yíì bẹ̀rẹ̀ láti òní títí di ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù yí.

Onidajo Tsoho tenumo pé ètò àmì ẹyẹ òpin ọdún àti ayẹyẹ idagbere yóò wáyé láti fi bu ọlá fún adajo àgbà ilé ẹjọ́ náà tẹ́lẹ̀rí Onidajo Adamu Abdul kafar to ṣẹ̀ṣẹ̀ feyinti.

Atejade náà tún se àfikún ẹ pé ọjọ́ ajé ọjọ́ keje oṣù tonbo nigbà tí ilé ẹjọ́ yóò bẹ̀rẹ̀ isẹ lejo kewá oṣù Kínní ọdún 2022.

Net / Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *