Home Posts tagged Ilé ẹjọ́ Gíga
News Yoruba

Ilé ẹjọ́ Gíga Ń Palemo Fún Ìsinmi ọdún

Ilé ẹjọ́ gíga ìjọba àpapọ̀ yíì bẹ̀rẹ̀ ètò ìsinmi lẹ́nu isẹ láti ogúnjó oṣù yí lọ. Nibamu pẹ̀lú atejade tí adajo àgbà ilé ẹjọ́ gíga ilẹ̀ yí òundajo John Tsoho fi síta, igbese ipalemo yíì bẹ̀rẹ̀ láti òní títí di ọjọ́ kẹrindínlógún oṣù yí. Onidajo Tsoho tenumo pé ètò àmì ẹyẹ òpin ọdún àti ayẹyẹ Continue Reading