Nidi ati wa ona abayo si isoro awon ewe to sa kuro nileewe lorileede yi, o se Pataki fawon toro eto eko gberu lati maa fowosowopo.

Alaga ajo eleto eko kariaye nipinle Oyo, Omowe Nureni Adeniran lo pepe yi lasiko iforowero pelu akorinyin Radio Nigeria fun ti isami ayajo eto eko lagbaye.

Omowe Adenitan kominu lori iye awon omode ti ko le sileewe mo inle Nigeria leyi ti won le ni milionu mewa, o salaye wipe ajo eleto eko kariaye nipinle Oyo ti n fowosowopo pelu ileese ijoba apapo feto eko ati Bank Agbaye lona ati mu adinku ba isoro naa.

Omowe Adeniran soo di mimo wipe won ti se idasile ibudo bii irinwo ati metadinlogorin kaakiri ijoba ibile to wa nipinle Oyo fun eto eko alabode fawon omode to n fere gbale oju popo atawon to n kiri oja pelu awon omo daran daran taa mo si Almajiri.

Alaga ajo SUBEB tenumo pea won akeko to wa nileewe ipinle Oyo ti po niye si nitori liana eto eko ofe tijoba Gomina Seyi Makinde kede re.

Omowe Adeniran tenumo pe igbese agbega eto eko ni kii se keremi, ko si lee je ojuse ijoba nikan, o w ape fun ifowosowopo awon tolohun segiola fun atawon akekoja ileewe fun agbega eto eko lapa

Kehinde /Saludeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *