Won ti gba ijoba apapo nimoran pe ki won sewele erongba afikun owo epo petirolu farailu nipa ati yo owo iranwon ori epo wo.

Oluso Aguntan ile Ijosin C.A.C. Power of the Cross, to wa lagbegbe Orogun nilu Ibadan, Pastor Joshua Aghene lo soro imoran yi lasiko takoroyin Radio Nigeria n foro wa lenuwo nipa ipo teto oro aje ile yi de duro ati ipa ti erongba ijoba lori yiyo owo iranwo lee mu ba awujo.

Ojise Olorun naa salaye wipe bi ise ohun osi se gogo lawujo n fe amojuto ni kiakia yato fun alekun owo epo petiroolu.

Oluso Aguntan Aghene tun kesi ijoba apapo pe ki won mu ayipada wa ba ona tile yi n gba pa owo wole latile okeere, palu ipenija eto aabo to n ba eka ise agbe finra.

Ojise Olorun na wa ro gbogbo omoleyin Christy pe ki won tera mo adura si Olorun lati da si oro orileede yi.

Famakin / Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *