Ajo eleto idibo nile yi, INECti kesi awon eeyan ile Nigeria lati pari iforukosile won feto idibo loju ojo leyin iforikosile ori eto ayelujara.

Olori leka idanileko ati oro-awujo lajo INEC nipinle Oyo, Arabinrin Catherin Ogwu so eyi lasiko to n kopa lori eto ilese Radio Nigeria kan Political Space.

Arabinrin ogwu ni, iye awon to foruko sile lori ero ayelujara je egberun lona adoje ole meta amo awon mejidinladorun pere loti pari iforukoosile won.

O war o awon oludibo lati seto iforuko sile won lojuna ati yan adari tooye, to si wu won ti yo se ijoba awa raw a to mina doko.

Arabinrin Ogwu wa sekilo fawon eeyan ile yi lati mase funle igbese sise iforukosile ju eekan lo, eyi to ni  o je iwa koto labe ofin idibo, pelu alaye pe o le mu ki ati gba cardi oludibo alalope lewu lopo.

Banjo/Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *