Yoruba

Àwọn araalu bèrè fún gbígba isẹ́ àgbàse òpópónà Àkúrẹ́ sí Adó Èkìtì kúrò lọ́wọ́ agbasẹ́ tó ńséè

Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Òndó àti Èkìtì ti sèwọde wọ́ọ̀rọ́wọ́ lórí bí wọ́n ti se pa isẹ́ sísọ opopona tó lọ láti ìlú Àkúrẹ́ sí Èkìtì oní billiọnu méjìlélógún naira tí èyítí ìjọba àpapọ̀ ti gbé fún agbasẹ́ se láti bí osù mẹ́ẹ̀dogún sẹ́yìn.

Àwọn olùwọ́de náà ni wọ́n yabo agbègbè igboba ni to si opopona ńlá tó wà nílu  Àkúrẹ́ láti fi àidúnú wọn hàn lórí ipò tí opopona náà wà.

Àwọn olùgbé náà fẹ́sùn kan agbasẹ́se pé ko ya sí isẹ́ náà láyiti wọ́n tí sanwó fún láti bíì osù mẹ́ẹ̀dogún sẹ́yìn.

Oniruru àkọ́lé bíì ìjínigbé àti ìfipábáni lòpọ̀ ti pọ̀jù lópopónà Àkúrẹ́ sí Adó Èkìtì, e gba isẹ́ sísọ opopona Àkúrẹ́ sí Adó Èkìtì di oníbejì kúrò lọ́wọ́ ẹnití ẹ gbe fún àti bẹ́ẹ̀ bẹ lọ.

Odún 2020 ni àarẹ Muhammadu Buhari gbé isẹ́ àgbàsẹ opopona náà fagbasẹ se fún ogún billiọnu naira.

Femi Dadamola

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *