Home Posts tagged Àarẹ Buhari
News Yoruba

Àarẹ Buhari Pàsẹ Fáwọn Olórí Ilé Isẹ́ Ètò Àbò Láti Gbé Pẹ́rẹ́gi Kaná Fáwọn Tó Ń Pagidínà Ètò Àbò

Àarẹ Muhamadu Buhari ti pàsẹ fáwọn àjọ aláàbo nílẹ̀yí láti tẹ̀síwájú lórí gbígbógun ti àwọn ẹni láàbi tó ń pagidínà ètò àbò títí tọ́rọ̀ náà yóò fi dafi seyi tẹ́ẹ̀gun alarẹ fisọ. Àarẹ sọ̀rọ̀ náà nílu Abuja lásìkò àbẹ̀wò àwọn olórí ilé isẹ́ èètò àbò sí lórí ibi tí ń kan dé dúró, àti àwọn […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari dáwọ́dùnú pẹ̀lú àwọn Mùsùlùmí lórí àyájọ́ ọdún Eid-el-Maulud

Bí àwọn Mùsùlùmí lórílẹ̀èdè yíì, se darapọ̀ mọ́ àwọn akẹgbẹ́ wọn lágbayé láti sayẹyẹ ọjọ́ ìbí ànọ́ọ̀bì. Àarẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì láti sàmúlò àkókò yíì, fíì nawọ́ ìfẹ́ sáwọn èèyàn wọn gẹ́gẹ́ bí àwòkóse ànọ́bì.  Nínú àtẹ̀gáde tí olùrànlọ́wọ́ pàtàkì fún àrẹ lórí ọ̀rọ̀ ìròyìn àti ìbáráalu sọ̀rọ̀, Garba Sheu […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari sèkìlọ̀ fáwọn ọ̀dàlúrú láti tọ́wọ ọmọ rẹ̀ bọsọ

  Àarẹ Muhammadu Buhari ti sèkìlọ̀ fáwọn ọ̀bàyéjẹ́ tí wọ́n gọ sábẹ́ ìfẹ̀hónúhàn EndSars fidá wàhálà sílẹ̀ lórílẹ̀èdè yíì láti tọwọ́ ọmọ wọn bọsọ.   Àarẹ ẹnitó sọ èyí nígbà tó ńbá àwọn èèyàn orílẹ̀èdè yíì sọ̀rọ̀, rọ́ọ̀ àwọn ọ̀dọ́ láti sẹ́wẹ́lé ìyansẹ́lódì tí wọ́n gùnlé.   Ó wá késí àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì láti máà báà kárà-kátà […]Continue Reading