Àjò ton mojuto ìdánwò síle ẹ̀kọ́ gíga vasiti nílè yíì JAMB tí gba ìwé àṣẹ ibùdó mọ́kànlá tí wọ́n ti ń ṣe ìdánwò náà padà lórí ẹ̀sùn pé wọ́n gba owó lọ́wọ́ àwọn akẹ́ko lórí iforukosile to lọ lọ́wọ́ fún ìdánwò. Ogagba àjọ òhún, Ojogbon Ishaq Oloyede ló sọ èyí di mímọ, lásìkò ifikùnlukùn pẹ̀lú Continue Reading
Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkèrè Ambassador Zubairu Dada, ti pè fún ìbásepọ̀ tó gbúmọ̀ láarin gbogbo àwọn lájọ-lájọ àti ẹ̀ka tó wà lábẹ́ ìsàkóso ọ̀rọ̀ nípa ilẹ̀ òkèrè. Ó sọ̀rọ̀ yí nílu Abuja, lásìkò tón gba àwọn ìgbìmọ̀ aláse ẹ̀ka àtò gbogbo nílẹ̀ adúláwọ̀ lálejò ní ófìsì rẹ̀. Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkèrè, Ambassador Dada […]Continue Reading